Ṣàwárí › Ìrìn-àjò › Ìrìn-àjò Jakọbu
Ìrìn-àjò
Ìrìn-àjò Jakọbu
Sí Harani àti padà, lẹ́yìn náà sọ̀kalẹ̀ lọ sí Ejibiti · Iye ibùdó: 13 · ≈ 1,790 km ní ìlà tààrà
Àwọn ibùdó
- 1
BeerṣebaGẹ 28:10Jakọbu kúrò ní Beerṣeba, ó sì kọrí sí ìlú Harani.
- 2
BeteliGẹ 28:19Ó sì pe orúkọ ibẹ̀ ní Beteli, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìlú náà ń jẹ́ Lusi tẹ́lẹ̀ rí.
- 3
HaraniGẹ 29:4Jakọbu béèrè lọ́wọ́ àwọn darandaran náà pé, “Ẹ̀yin arákùnrin mi níbo ni ẹ̀yin ti wá?” Àwọn náà sì dáhùn pé, “Láti Harani ni.”
- 4
GileadiGẹ 31:21Ó sì sálọ pẹ̀lú ohun gbogbo tí ó ni, ó sì la odò kọjá (Eufurate), ó sì kọrí sí àwọn ilẹ̀ olókè ti Gileadi.
- 5
MahanaimuGẹ 32:2Nígbà tí Jakọbu rí wọn, ó wí pé, “Àgọ́ Ọlọ́run ni èyí!” Ó sì pe orúkọ ibẹ̀ ni Mahanaimu.
- 6
PenieliGẹ 32:30Jakọbu sì pe orúkọ ibẹ̀ ní Penieli pé, “Mo rí Ọlọ́run ní ojúkojú, síbẹ̀ a dá ẹ̀mí mi sí.”
- 7
SukkotiGẹ 33:17Jakọbu sì lọ sí Sukkoti, ó sì kọ́ ilé fún ara rẹ̀, ó sì ṣe ọgbà fún àwọn ẹran. Ìdí èyí ní a fi ń pe ibẹ̀ ní Sukkoti.
- 8
ṢekemuGẹ 33:18Lẹ́yìn ìgbà tí Jakọbu tí Padani-Aramu dé, àlàáfíà ni Jakọbu dé ìlú Ṣekemu ní ilẹ̀ Kenaani, ó sì pàgọ́ sí itòsí ìlú náà.
- 9
BeteliGẹ 35:6Jakọbu àti gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ sì dé sí Lusi (ti o túmọ̀ sí Beteli) tí ó wà ní ilẹ̀ Kenaani.
- 10
BẹtilẹhẹmuGẹ 35:19Báyìí ni Rakeli kú, a sì sin ín sí ọ̀nà Efrata (ti o túmọ̀ sí, Bẹtilẹhẹmu).
- 11
HebroniGẹ 35:27Jakọbu sì padà dé ilé lọ́dọ̀ Isaaki baba rẹ̀ ni Mamre nítòsí i Kiriati-Arba (ti o túmọ̀ sí Hebroni). Níbi tí Abrahamu àti Isaaki gbé.
- 12
BeerṣebaGẹ 46:1Báyìí ni Israẹli mú ìrìnàjò rẹ̀ pọ̀n pẹ̀lú ohun gbogbo tí ó ní, nígbà tí ó sì dé Beerṣeba, ó rú ẹbọ sí Ọlọ́run Isaaki baba rẹ̀.
- 13
GoṣeniGẹ 46:28Jakọbu sì rán Juda ṣáájú rẹ̀ lọ sọ́dọ̀ Josẹfu, kí wọn bá à le mọ ọ̀nà Goṣeni. Nígbà tí wọ́n dé agbègbè Goṣeni,
Àwọn ìlà so àwọn ibùdó pọ̀ ní ìtẹ̀léra ọ̀rọ̀ Bíbélì — a kò mọ àwọn ọ̀nà gan-an. Ìlà tí a gé: nínú ọkọ̀ ojú omi. Àwọ̀ tí kò ṣe kedere: a kò mọ̀ dájú ibi náà.
Àmì kọ̀ọ̀kan ni ibi tí ó ṣeé ṣe jùlọ (OpenBible.info); àmì tí àwọ̀ rẹ̀ kò ṣe kedere túmọ̀ sí pé a kò mọ̀ dájú. Àwọn ibi tí a kò mọ ibi tí wọ́n wà kò sí lórí máàpù.
Ibi tí wọ́n wà: OpenBible.info Bible Geocoding Data (CC BY 4.0).
Ààlà ilẹ̀: Natural Earth (ohun ìní gbogbo ènìyàn).