Òrùlé Àpáta lórí Òkè Tẹ́ńpìlì, èyí tí àṣà fi wé òkè Moráyà, lókè ògiri ìlú. Fọ́tò láti ọwọ́ Felice Beato, 1856–57.
Àwọn fọ́tò àkọ́kọ́, ọdún 1850–1870
Òrùlé Àpáta, tí a ń pè ní «mọ́ṣáláṣí Omar» nígbà náà, lórí Òkè Tẹ́ńpìlì. Fọ́tò láti ọwọ́ Francis Frith, 1857.Òkè Tẹ́ńpìlì, èyí tí àṣà fi wé òkè Moráyà, bí a ti rí i láti kànga Ẹni-Rógẹ́lì ní àfonífojì Kídírónì. Fọ́tò láti ọwọ́ Francis Frith, ní nǹkan bí 1857.